Micheal

Akalamagbo sebe o mu eran lo
Erin wo nigbo
Eranko igbo bosokun

Advertisements

And away He flew.
Bi akalamagbo,
Iwo ti je ipe iku
Oo tie boju wehin
Ko ti e wo awon to file

Like a thief in the night
A flash of lightening
A quick dash outside
You made your exit.

Iwo ti lo ajule orun
O je ipe awon egbe re t’ohun
O fi awon egbe re t’ihin le
Oo ti bo ju wehin.
Oo daro rara
Iku sebe o mu elo.
O da wa si ekun osan gangaan

Tani ko ba ma je ipe bi ko se wo?
Yesi eni iba mu iku lare?
Iwo se be, o ba sure
Bo ba ti e ma ba sure
Oo tie ti jeun k’oyo
K’o je ku fawon omo
Oo ti dun baba ninu
Ko mu iya yangan ,lawujo ore
Ko mu ara se apejuwe
Ki gbogbo omo danihan ti e to iyo re wo

Mikeli, omo Osunjuyigbe
O mu iku lowo
O fi yen se agba wa.
Oo ti dagbere fun awon ore
Ko faya sile ko to rin irin ajo.

Ko fun ara ile lebi
Ko fun ara owun l’aro ro.

Iro o!
Iwo je ipe eye
Akalamagbo ti o ba igun je
Igun se be o mu eran lo
Erin wo nigbo
Eran igbo bu s’okun.

Ki lawa o ba ma fi’pitan l’ojo oni?

Leave a Reply

Fill in your details below or click an icon to log in:

WordPress.com Logo

You are commenting using your WordPress.com account. Log Out /  Change )

Google photo

You are commenting using your Google account. Log Out /  Change )

Twitter picture

You are commenting using your Twitter account. Log Out /  Change )

Facebook photo

You are commenting using your Facebook account. Log Out /  Change )

Connecting to %s